Ìfìwéránsẹ́ tó ṣẹ̀ṣẹ̀ wọlé
Asegbe kan o si, asepamo lowa
ÒWÉ
Kò sí ohun aburú kan tí a ṣe tí yóò pamọ́ títí láé, gbogbo rẹ̀ ni yóò padà wá sí orí ẹni.
Iṣe ènìyàn ní ń tẹ̀lé e.
Owe yìí ń rán wa létí láti máa ṣe rere ní gbogbo ìgbà.
By: Esteri
Jan 24, 2026 • 3:50 PM
Awọn idahun (0)
Wo ile lati fesi.