Ìfìwéránsẹ́ tó ṣẹ̀ṣẹ̀ wọlé
ÒWE
ÒWÉ FUN ERE ITAGE KUKURU
Ọmọ ẹlẹ́mu tó fọ́ akèrègbè, ohun tó dun bàbá ẹ̀ ló ṣe. Ọ̀rọ̀ bí ọ̀rọ̀ akèrègbè ló ń dun ẹlẹ́mu.
(A palm wine tapper’s child who shatters the gourds has done what displeases his father the most. Gourds are a matter that pains tappers beyond words.)
It's important to honour what others value greatly or depend on, especially when such things are entrusted to you. The smallest act of carelessness can destroy a lifetime of work. The people we trust most have the power to wound us most deeply. Therefore, responsibilities and relationships have to be handled with utmost care.
By: Agbotuedo Ebenezer Taiwo
May 9, 2026 • 6:13 AM
Awọn idahun (0)
Wo ile lati fesi.